Ìṣe Àwọn Aposteli 7:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n gbé òkú wọn lọ sí Ṣekemu, wọ́n sin wọ́n sinu ibojì tí Abrahamu fowó rà lọ́wọ́ àwọn ọmọ Hamori ní Ṣekemu.

Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:8-17