Ìṣe Àwọn Aposteli 5:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni ẹ̀tanú gba ọkàn Olórí Alufaa ati gbogbo àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Sadusi tí ó wà pẹlu rẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 5

Ìṣe Àwọn Aposteli 5:16-23