Ìṣe Àwọn Aposteli 4:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkàn kan ati ẹ̀mí kan ni gbogbo àwùjọ àwọn onigbagbọ ní. Kò sí ẹnìkan ninu wọn tí ó dá àwọn nǹkan tirẹ̀ yà sọ́tọ̀, wọ́n jọ ní gbogbo nǹkan papọ̀ ni.

Ìṣe Àwọn Aposteli 4

Ìṣe Àwọn Aposteli 4:25-37