Ìṣe Àwọn Aposteli 28:14 BIBELI MIMỌ (BM)

A rí àwọn onigbagbọ níbẹ̀. Wọ́n rọ̀ wá kí á dúró lọ́dọ̀ wọn, a bá ṣe ọ̀sẹ̀ kan níbẹ̀. Báyìí ni a ṣe dé Romu.

Ìṣe Àwọn Aposteli 28

Ìṣe Àwọn Aposteli 28:6-15