Ìṣe Àwọn Aposteli 27:10 BIBELI MIMỌ (BM)

ó ní, “Ẹ̀yin ará, mo wòye pé ewu wà ninu ìrìn àjò yìí. Ọpọlọpọ nǹkan ni yóo ṣòfò: ẹrù inú ọkọ̀, ati ọkọ̀ fúnrarẹ̀. Ewu wà fún gbogbo àwa tí a wà ninu ọkọ̀ pàápàá.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 27

Ìṣe Àwọn Aposteli 27:3-17