Ìṣe Àwọn Aposteli 22:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọ̀gágun bá lọ bi Paulu, ó ní, “Wí kí n gbọ́, ọmọ-ìbílẹ̀ Romu ni ọ́?”Paulu dáhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 22

Ìṣe Àwọn Aposteli 22:23-30