Ìṣe Àwọn Aposteli 22:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Oluwa sọ fún mi pé, ‘Bọ́ sọ́nà, nítorí n óo rán ọ lọ sí ọ̀nà jíjìn, sí ọ̀dọ̀ àwọn tí kì í ṣe Juu.’ ”

Ìṣe Àwọn Aposteli 22

Ìṣe Àwọn Aposteli 22:18-26