Ìṣe Àwọn Aposteli 22:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó dúró tì mí, ó ní, ‘Saulu arakunrin, lajú!’ Lẹsẹkẹsẹ ojú mi là, mo bá gbójú sókè wò ó.

Ìṣe Àwọn Aposteli 22

Ìṣe Àwọn Aposteli 22:11-23