Ìṣe Àwọn Aposteli 20:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ṣe oṣù mẹta níbẹ̀. Bí ó ti fẹ́ máa lọ sí Siria, ó rí i pé àwọn Juu ń dìtẹ̀ sí òun, ó bá gba Masedonia pada.

Ìṣe Àwọn Aposteli 20

Ìṣe Àwọn Aposteli 20:1-11