Ìṣe Àwọn Aposteli 20:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo mọ̀ pé lẹ́yìn tí mo bá lọ, àwọn ẹhànnà ìkookò yóo wọ ààrin yín; wọn kò sì ní dá agbo sí.

Ìṣe Àwọn Aposteli 20

Ìṣe Àwọn Aposteli 20:25-34