Ìṣe Àwọn Aposteli 2:43 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀rù àwọn onigbagbọ wá ń ba gbogbo eniyan. Ọpọlọpọ ni iṣẹ́ ìyanu ati iṣẹ́ abàmì tí a ti ọwọ́ àwọn aposteli ṣe.

Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Ìṣe Àwọn Aposteli 2:42-46