Ìṣe Àwọn Aposteli 17:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun tí ó dá ayé ati gbogbo nǹkan tí ó wà ninu rẹ̀, Oluwa ọ̀run ati ayé, kì í gbé ilé oriṣa àfọwọ́kọ́;

Ìṣe Àwọn Aposteli 17

Ìṣe Àwọn Aposteli 17:20-30