Ìṣe Àwọn Aposteli 16:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ilẹ̀ mọ́, àwọn adájọ́ rán àwọn iranṣẹ sí ẹni tí ń ṣọ́ ilé ẹ̀wọ̀n pé, kí ó dá àwọn eniyan náà sílẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 16

Ìṣe Àwọn Aposteli 16:33-36