Ìṣe Àwọn Aposteli 16:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn olówó ọdọmọbinrin náà rí i pé ọ̀nà oúnjẹ wọ́n ti dí, wọ́n ki Paulu ati Sila mọ́lẹ̀, wọ́n fà wọ́n lọ sọ́dọ̀ àwọn aláṣẹ ní ọjà.

Ìṣe Àwọn Aposteli 16

Ìṣe Àwọn Aposteli 16:16-25