Ìṣe Àwọn Aposteli 16:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní Ọjọ́ Ìsinmi a jáde lọ sẹ́yìn odi ìlú lẹ́bàá odò, níbi tí a rò pé a óo ti rí ibi tí wọn máa ń gbadura. A bá jókòó, a bá àwọn obinrin tí ó péjọ níbẹ̀ sọ̀rọ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 16

Ìṣe Àwọn Aposteli 16:11-23