Ìṣe Àwọn Aposteli 15:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n kà á, inú wọn dùn sí ọ̀rọ̀ ìyànjú tí ó wà ninu rẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 15

Ìṣe Àwọn Aposteli 15:24-38