Ìṣe Àwọn Aposteli 13:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n dé Salami, wọ́n waasu ọ̀rọ̀ Ọlọrun ninu àwọn ilé ìpàdé àwọn Juu. Wọ́n mú Johanu lọ́wọ́ kí wọn lè máa rí i rán níṣẹ́.

Ìṣe Àwọn Aposteli 13

Ìṣe Àwọn Aposteli 13:1-14