Ìṣe Àwọn Aposteli 12:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ilẹ̀ mọ́, ìdààmú ńlá bá àwọn ọmọ-ogun. Wọn kò mọ ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí Peteru.

Ìṣe Àwọn Aposteli 12

Ìṣe Àwọn Aposteli 12:8-24