Ìṣe Àwọn Aposteli 12:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ojú Peteru wá wálẹ̀. Ó ní, “Mo wá mọ̀ nítòótọ́ pé Oluwa ni ó rán angẹli rẹ̀ láti gbà mí lọ́wọ́ Hẹrọdu, ati láti yọ mí kúrò ninu ohun gbogbo tí àwọn Juu ti ń retí.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 12

Ìṣe Àwọn Aposteli 12:4-14