Ìṣe Àwọn Aposteli 12:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ní àkókò náà Hẹrọdu ọba bẹ̀rẹ̀ sí ṣe inúnibíni sí àwọn kan ninu ìjọ.

2. Ó bẹ́ Jakọbu arakunrin Johanu lórí.

3. Nígbà tí ó rí i pé ó dùn mọ́ àwọn Juu, ó bá tún mú Peteru náà. Àkókò náà ni Àjọ̀dún Àìwúkàrà.

Ìṣe Àwọn Aposteli 12