Ìṣe Àwọn Aposteli 11:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Lákòókò náà gan-an ni àwọn ọkunrin mẹta tí a rán sí mi láti Kesaria dé ilé tí mo wà.

Ìṣe Àwọn Aposteli 11

Ìṣe Àwọn Aposteli 11:10-15