Ìṣe Àwọn Aposteli 10:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohùn náà tún dún létí rẹ̀ lẹẹkeji pé, “Ohun tí Ọlọrun bá ti sọ di mímọ́, o kò gbọdọ̀ pè é ní ohun àìmọ́!”

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:5-16