Ìṣe Àwọn Aposteli 10:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ebi dé sí i, ó wá ń wá nǹkan tí yóo jẹ. Bí wọ́n ti ń tọ́jú oúnjẹ lọ́wọ́, Peteru bá rí ìran kan.

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:1-20