Hosia 4:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìyà kan náà ni ẹ̀yin alufaa ati àwọn eniyan yóo jẹ, n óo jẹ yín níyà nítorí ìwà burúkú yín, n óo sì gbẹ̀san lára yín nítorí ìṣe yín.

Hosia 4

Hosia 4:1-15