Hosia 14:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn óo pada sábẹ́ ààbò mi,wọn óo rúwé bí igi inú ọgbà;wọn óo sì tanná bí àjàrà,òórùn wọn óo dàbí ti waini Lẹbanoni.

Hosia 14

Hosia 14:2-9