Heberu 10:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ̀yin ará, a ní ìgboyà láti wọ Ibi Mímọ́ jùlọ tí ó wà lẹ́yìn aṣọ ìkélé nípa ẹ̀jẹ̀ Jesu,

Heberu 10

Heberu 10:12-24