Filipi 2:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ọkàn gbogbo yín ń fà á, ọkàn rẹ̀ kò sì balẹ̀ nítorí gbígbọ́ tí ẹ ti gbọ́ pé ó ṣàìsàn.

Filipi 2

Filipi 2:22-30