Ẹsira 8:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Àkọsílẹ̀ àwọn eniyan ati àwọn baálé baálé tí wọ́n bá mi pada wá láti Babiloni ní àkókò Atasasesi, ọba, nìyí:

Ẹsira 8

Ẹsira 8:1-7