Ẹkún Jeremaya 2:5 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ṣe bí ọ̀tá,ó ti pa Israẹli run.Ó ti pa gbogbo ààfin rẹ̀ run,ó sọ àwọn ibi ààbò rẹ̀ di àlàpàó sì sọ ọ̀fọ̀ ati ẹkún Juda di pupọ.

Ẹkún Jeremaya 2

Ẹkún Jeremaya 2:1-7