Ẹkisodu 39:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà wọ́n da òrùka wúrà meji, wọ́n sì dè wọ́n mọ́ etí kinni keji ìgbàyà náà, lọ́wọ́ inú ní ẹ̀gbẹ́ tí ó kan ara efodu.

Ẹkisodu 39

Ẹkisodu 39:11-27