Ẹkisodu 31:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, àwọn eniyan Israẹli yóo máa pa ọjọ́ ìsinmi mọ́, wọn yóo máa ranti rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àmì majẹmu ní ìrandíran wọn.

Ẹkisodu 31

Ẹkisodu 31:9-18