Ẹkisodu 3:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Mose dá Ọlọrun lóhùn pé, “Ta ni mo jẹ́, tí n óo fi wá tọ Farao lọ pé mo fẹ́ kó àwọn ọmọ Israẹli kúrò ní ilẹ̀ Ijipti?”

Ẹkisodu 3

Ẹkisodu 3:6-19