Ẹkisodu 2:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose gbà láti máa gbé ọ̀dọ̀ ọkunrin náà, ó bá fún un ní Sipora, ọ̀kan ninu àwọn ọmọbinrin rẹ̀ láti fi ṣe aya.

Ẹkisodu 2

Ẹkisodu 2:20-25