Ẹkisodu 14:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará Ijipti lé wọn wọ inú òkun, tàwọn ti gbogbo ẹṣin Farao ati gbogbo kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀ ati gbogbo ẹlẹ́ṣin rẹ̀.

Ẹkisodu 14

Ẹkisodu 14:16-30