Ẹkisodu 1:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwọn agbẹ̀bí náà bẹ̀rù Ọlọrun; wọn kò tẹ̀lé àṣẹ tí ọba Ijipti pa fún wọn, pé kí wọn máa pa àwọn ọmọkunrin tí àwọn obinrin Heberu bá ń bí.

Ẹkisodu 1

Ẹkisodu 1:14-20