Efesu 6:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ẹ̀yin ọmọ, ẹ máa gbọ́ ti àwọn òbí yín nítorí pé bẹ́ẹ̀ ni ó dára.

2. “Bọ̀wọ̀ fún baba ati ìyá rẹ.” Èyí níí ṣe òfin kinni pẹlu ìlérí, pé

3. “Kí ó lè dára fún ọ, ati kí o lè pẹ́ lórí ilẹ̀ náà.”

Efesu 6