Diutaronomi 5:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Mose pe gbogbo àwọn ọmọ Israẹli jọ, ó wí fún wọn pé, “Ẹ̀yin ọmọ Israẹli, ẹ gbọ́ àwọn ìlànà ati àwọn òfin tí n óo kà fun yín lónìí; ẹ kọ́ wọn, kí ẹ sì rí i pé ẹ̀ ń tẹ̀lé wọn.

2. OLUWA Ọlọrun wa bá wa dá majẹmu kan ní òkè Horebu.

Diutaronomi 5