Diutaronomi 29:24 BIBELI MIMỌ (BM)

gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè ni yóo máa bèèrè pé, ‘Kí ló dé tí OLUWA fi sọ ilẹ̀ yìí dà báyìí? Kí ló dé tí ibinu ńlá OLUWA fi dé sórí ilẹ̀ yìí?’

Diutaronomi 29

Diutaronomi 29:21-29