Diutaronomi 25:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn kò bẹ̀rù Ọlọrun, ṣugbọn wọ́n gbógun tì yín lójú ọ̀nà nígbà tí ó ti rẹ̀ yín, wọ́n sì pa gbogbo àwọn tí wọn ń bọ̀ lẹ́yìn.

Diutaronomi 25

Diutaronomi 25:14-19