Diutaronomi 23:15 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí ẹrú kan bá sá kúrò lọ́dọ̀ ọ̀gá rẹ̀, tí ó bá tọ̀ yín wá, ẹ kò gbọdọ̀ lé e pada sọ́dọ̀ ọ̀gá rẹ̀.

Diutaronomi 23

Diutaronomi 23:5-20