Diutaronomi 2:34 BIBELI MIMỌ (BM)

A gba àwọn ìlú ńláńlá rẹ̀ nígbà náà, a sì run wọ́n, ati ọkunrin, ati obinrin, ati àwọn ọmọ wọn. A kò dá ohunkohun sí,

Diutaronomi 2

Diutaronomi 2:25-37