Diutaronomi 17:3 BIBELI MIMỌ (BM)

bí ó bá lọ bọ oriṣa, kì báà ṣe oòrùn, tabi òṣùpá, tabi ọ̀kan ninu àwọn nǹkan mìíràn tí ó wà ní ojú ọ̀run, tí mo ti pàṣẹ pé ẹ kò gbọdọ̀ bọ;

Diutaronomi 17

Diutaronomi 17:2-12