Daniẹli 5:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí ó gbé ara rẹ̀ ga, tí ó sì ṣe oríkunkun, a mú un kúrò lórí ìtẹ́ rẹ̀, a sì mú ògo rẹ̀ kúrò.

Daniẹli 5

Daniẹli 5:13-25