Daniẹli 2:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohun tí ọba ń bèèrè yìí le pupọ, kò sí ẹni tí ó lè ṣe é, àfi àwọn oriṣa, nítorí pé àwọn kì í ṣe ẹlẹ́ran ara.”

Daniẹli 2

Daniẹli 2:3-21