Daniẹli 10:17 BIBELI MIMỌ (BM)

N kò ní agbára kankan mọ́, kò sì sí èémí kankan ninu mi, báwo ni èmi iranṣẹ rẹ ti ṣe lè bá ìwọ oluwa mi sọ̀rọ̀?”

Daniẹli 10

Daniẹli 10:7-21