Daniẹli 1:20-21 BIBELI MIMỌ (BM)

20. Ninu gbogbo ọ̀rọ̀ ọgbọ́n ati ìmọ̀ tí ọba bi wọ́n, ó rí i pé wọ́n sàn ní ìlọ́po mẹ́wàá ju gbogbo àwọn pidánpidán ati àwọn aláfọ̀ṣẹ tí ó wà ní ìjọba rẹ̀ lọ.

21. Daniẹli sì wà níbẹ̀ títí di ọdún kinni ìjọba Kirusi.

Daniẹli 1