Àwọn Ọba Kinni 8:47 BIBELI MIMỌ (BM)

bí wọ́n bá ronupiwada ní ilẹ̀ tí wọ́n kó wọn lẹ́rú lọ, tí wọ́n sì rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí ọ, tí wọ́n bá jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n dá, ati ìwà burúkú tí wọ́n hù,

Àwọn Ọba Kinni 8

Àwọn Ọba Kinni 8:37-49