Àwọn Ọba Kinni 8:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo ti ṣètò ibìkan ninu ilé náà fún Àpótí Ẹ̀rí OLUWA, tí tabili òkúta tí wọ́n kọ majẹmu sí wà ninu rẹ̀, majẹmu tí OLUWA bá àwọn baba ńlá wa dá nígbà tí ó ń kó wọn jáde láti ilẹ̀ Ijipti.”

Àwọn Ọba Kinni 8

Àwọn Ọba Kinni 8:20-27