Àwọn Ọba Kinni 7:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Huramu tún fi bàbà ṣe ìtẹ́lẹ̀ mẹ́wàá, ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn gùn ní igbọnwọ mẹrin, wọ́n fẹ̀ ní igbọnwọ mẹrin, wọ́n sì ga ní igbọnwọ mẹta.

Àwọn Ọba Kinni 7

Àwọn Ọba Kinni 7:23-33