Àwọn Ọba Kinni 5:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó fi Adoniramu ṣe alabojuto wọn. Ó pín wọn sí ọ̀nà mẹta: ẹgbaarun (10,000) ọkunrin ní ìpín kọ̀ọ̀kan. Ìpín kọ̀ọ̀kan a máa ṣiṣẹ́ fún oṣù kan ní Lẹbanoni, wọn á sì pada sílé fún oṣù meji.

Àwọn Ọba Kinni 5

Àwọn Ọba Kinni 5:9-18